9ice – Iwaju Lyrics
It’s Dtunes again
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
want song, wants favour
e maa ríran wò ti n ba k’orin
mo rí èèmọ l’agege, ajá w’ewu o roṣọ
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
ẹnu ẹni laa fi kọ meejẹ̀
ẹnu ẹni...
This site uses cookies to help personalise content, tailor your experience and to keep you logged in if you register. By continuing to use this site, you are consenting to our use of cookies.